Şèkèrè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

ŞÈKÈRÈ Je ohun èlò orin ibileYoruba ti Oloogbe Alaaji Alamu Atatalo lati Ibadan, Naijiria je Oludasile ati Agbateru re. .owo-eyo ni won to Sara agbe ti o n dan, Akorin/olorin a maa MI sekerekikankikan, bee ni a maa lo igori ikaowo re lati lu agbe naa lati mu ohun didun, ti o n mu ayo ati idunnu wa sokan awon onworan. Olorin sekere tun maa lo awon ohun-elo orin mii bi I aro, dundun, omole agogo agidigbo gege bi egbe orin ni ileYoruba-ni pato ni Ibadan awon olorin sekere nigba mii maa n fi aseregee won han nigba ti won baju sekere soke soju ofurufu,ti won a si han-an lati fi bi idunnu won se po to han.[1] se patakilati fi kun-un p e sekere gege bi ohun-elo orin yato gedegbe. Si agbe kekere/ado(pelu orisiiri iakosile won ti o wa. niOrile-edeCuban,Brazil ati awon apa ileAfrika. Ohun-elo orin ti a sapejuwe re yi je ohun oto ni Ile Yoruba ti o wa niOrile-ede Naijiria paapaa julo ni Ibadan.

Ìtóka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Sekere
  1. "SAMUẸLI KEJI 6:5 Dafidi ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bẹ̀rẹ̀ sí jó níwájú OLUWA, wọ́n sì ń kọrin pẹlu gbogbo agbára wọn. Wọ́n ń lu àwọn ohun èlò orin olókùn tí wọ́n ń pè ní hapu, ati lire; ati ìlù, ati ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ati aro - Download The Bible App Now". Yoruba Bible (BM) (in Èdè Latini). Retrieved 2019-03-14.