Jump to content

Ṣèyí Ẹdun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ṣèyí Ẹdun tí àpèjá orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwaṣẹ̀yí Ẹdun tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹfà ọdún (4th June) jẹ́ gbajúmò òṣèrébìrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Ayétòrò ní Ìpínlẹ̀ ÒGÙN lórílẹ̀-èdè NÀÌJÍRÍÀ. [1]. Òun ni ìyàwó gbajúmọ̀ Òṣerékùnrin Adéníyì Johnson. [2]

Ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

ṣèyí Ẹdun jẹ́ ọmọ bíbí Ayétòrò, nílẹ̀ Yewa, ní Ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí dìgírí nínú ìmọ̀ Olùkọ́ ní Ifáfitì Ọlábísí Ọ̀nàbánjọ ní Ìpínlẹ̀ Ọgùn. Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ òun fúnra rẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 2008 wọnú 2009,nígbà tí ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tíátà tí wọ́n ń pè ní Wisdom Caucus. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa láti ìgbà náà. [1]

Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ògo Ọlọ́run
  • Ẹja ńlá
  • Game master
  • Dárà
  • Four couples
  • Ìbídùn Ọlọ́kà
  • Irú kan náà
  • Ẹni ìtàn
  • Wọnúọlá
  • Aṣẹ́wó
  • Ọkọ ọ̀ mi, ọ̀tá mi
  • Ọmọ ọ̀ mi
  • Àlè
  • Yọ̀mádé
  • Oníṣẹ́
  • Aláàánú
  • Ìyàwó tèmi
  • Gbajúmọ̀
  • Àmọ̀rí
  • Ojifiri
  • Amnesia
  • Abẹ̀bẹ̀
  • Boss lady
  • Tùmínínú
  • Kútì
  • Ex-fiance

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "BIOGRAPHY". OLUWASEYI EDUN. Retrieved 2020-05-22. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "Johnson’s, Seyi Edun’s love waxes stronger". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Latini). 2020-02-28. Retrieved 2020-05-22.