Ẹ̀kọ́ aṣísílẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ẹ̀kọ́ aṣísílẹ̀ jẹ́ ọ̀rọ̀ akọ́jọpọ̀ tó ùjtóka sí àwọn irú ẹ̀kọ́ níbi tí ìmọ̀, àwọn àrọ̀wá tàbí àwọn apá pàtàkì ọ̀rọ̀-ọ̀nà ìkọ̀lẹ́kọ̀ọ́ tàbi òpọ́onú lílò papọ̀ lọ́ọ̀fẹ́ lórí internet.

Ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú áwọn àdárọ̀ bíi Creative Commons, orísún aṣísílẹ̀, dátà aṣísílẹ̀ àti Ìgbàwọlé aṣísílẹ̀, wọ́n sì tún múpọ̀ mọ́ ìkọ̀ni àti àwọn courseware míràn.

Ẹ tún wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]