Ẹgbẹ́ olóṣèlú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ẹgbẹ́ olóṣèlú je agbajo oloselu kan to n wa lati gba ati lo agbara iselu ninu ijoba, nipa pipolongo idiboyan, eko aralu tabi iseakitiyan. Awon egbe oloselu le ni ero iselu ti won ko sinu eto egbe oloselu to ni ohun pato ti won fe se ninu eyi to ko gbogbo won papo.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]