Ẹlẹ́sìn Krístì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ẹlẹ́sìn Krístì

Ẹlẹ́sìn Kírísítì tàbí Ọmọ lẹ́yìn Kírísítì tàbí ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ni eni tó nígbàgbọ́ nínú Ẹ̀sìn Kírísítì èyí tó jẹ́ ẹ̀sìn Abrahamu tó gbà pé Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà tó ń darí ayé àti ẹ̀kọ́ Jésù ọmọ Násárétì tí wọ́n gbà bí Messiah tó jẹ́ sísọ tẹ́lẹ̀ nínú Májẹ̀mú Láéláé, àti Ọmọ Ọlọ́run.[1][2]Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. define.asp?key=13408&dict=CALD&topic=followers-of-religious-groups "Definition of Christian" Check |url= value (help). Cambridge Advanced Learner's Dictionary. Cambridge University Press. Retrieved 2010-18-01.  Check date values in: |access-date= (help)
  2. "BBC — Religion & Ethics — Christianity at a glance", BBC