Jump to content

Ọ̀gà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọ̀gà tí a tún lè pè ní Agẹmọ jẹ́ eranko kan tó farajọ alángbá, ṣùgbọ́n tí ó ní àbùdá kan tí ó lè fi pàrọ̀ àwọ̀ èyíkéyí tí ó bá fẹ́. [1] Ọ̀gà lè lò tó ọdún mẹ́ta sí márù-ún kí ó tó kú. [2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Chameleon". Wikipedia. 2003-01-27. Retrieved 2019-09-27. 
  2. Davis, Jen (2013-07-18). "On Average, How Long Do Chameleons Live?". Animals. Retrieved 2019-09-27.