Alángbá
Appearance
Lizards | |
---|---|
Clockwise from top left: veiled chameleon (Chamaeleo calyptratus), rock monitor (Varanus albigularis), common blue-tongued skink (Tiliqua scincoides), Italian wall lizard (Podarcis sicula), giant leaf-tailed gecko (Uroplatus fimbriatus), and legless lizard (Anelytropsis papillosus) | |
Scientific classification | |
Taxonomy not available for Squamata; please create it automated assistant | |
Groups included | |
Range of the lizards, all species
Many, see text | |
Legless squamates that are not considered lizards | |
Synonyms | |
Sauria Macartney, 1802 |
Alángbá jẹ́ ọ̀kan lára ẹbí lángbá tí ẹ̀yà wọn tó 300 níye. Irúfẹ́ Alángbá yí wọ́pọ̀ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀, Éṣíà, Australia, àti diẹ̀ ní agbègbè Southern Europe. Ọ̀pọ̀ nínú àwọn alángbá yí ni wọ́n ma ń pè (dragon) nítorí ìrísí wọn. [1][2]
ó fara jọ Ọ̀gà, ṣùgbọ́n tí kìí yí àwọ̀ padà bí Ọ̀gà Ìwádìí sáyẹ́nsì fihàn pé ó tó oríṣi ẹgbẹ̀rún mẹ́fà Ọ̀gà ló wà káàkiri gbogbo àgbáyé. [3][4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ananjeva, Natalia B.; Bryan L. Stuart (2001). "The Agamid lizard Ptyctolaemus phuwtilmensis Manthey and Nabhitabhata, 1991 from Thailand and Laos represents a new genus". Russian Journal of Herpetology (Folium Publishing Company) 8 (3): 165–170. http://www.suethedinosaur.org/research_collections/zoology/pdf/Ananjeva_Stuart_2001v2.pdf. Retrieved 4 November 2009.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Thompson, M.B. (1993). "Estimate of the population structure of the e[a]stern water dragon, Physignathus lesueurii (Reptilia : Agamidae), along riverside habitat". Wildlife Research 20 (5): 613–619. doi:10.1071/WR9930613.
- ↑ "THE REPTILE DATABASE". THE REPTILE DATABASE. 2019-12-21. Retrieved 2020-02-27.
- ↑ "The world's top 10 reptiles – in pictures". the Guardian. 2016-05-05. Retrieved 2020-02-27.