Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà àti àwọn irú ọ̀gẹ̀dẹ̀ míràn
Osi de otun: Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà, ogede pupa, ogede wewe, Cavendish bananas.
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
(unranked):
(unranked):
(unranked):
Ìtò:
Ìdílé:
Ìbátan:
Irú:
M. paradisiaca
Ìfúnlórúkọ méjì
Musa × paradisiaca

Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà (Musa × paradisiaca), jẹ́ èso kan lára èso igi oko nínú ìran Musa tó ṣe é sè jẹ, bójẹ lásán, dín, yan tàb lò fún Ó jẹ bí òkèlè. Ó yàtọ̀ sí àwọn ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹẹrẹ tó ṣe é fi ṣe ìpanu.


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]