Jump to content

Ọ̀rọ̀:DJ Xclusive

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àtúngbéyẹ̀wò àyọkà

[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹnlẹ́ o @Lulified Produkt, Inú wa dùn sí àwọn iṣẹ́ tí ẹ ń gbé ṣe lórí Wikipedia Yorùbá. A sì kí yín fún akitiyan yín lórí kíkọ àwọn àyọkà titun sílẹ̀. Àmọ́ ṣá, a ní ìwòye, àríwísí lórí àwọn iṣẹ́ ati gbogbo àyọkà yín. A ṣà'kíyèsí wípé:

  1. Irinṣẹ́ Google ni ẹ lò láti fi da àwọn àyọkà yín sílẹ̀ tí ó fi mọ́ DJ Xclusive.

A rọ̀ yín kí ẹ tún àwọn àyọkà yí kọ kí ó lè dùn ún kà fún àwọn ònkà Wikipedia Yoruba. A sì rọ̀ yín kí ẹ má ṣe dá àwọn àtúnṣe gidi tí àwọn aláfikún mìíràn bá ṣe lórí àwọn àyọkà tí ẹ bá ti kọ tẹ́lẹ̀. Bí ẹ bá ní ìbéèrè kan tàbí òmíràn, ẹ jọ̀wọ́ ẹ kàn sí mi. Ẹ ṣeun púpọ̀.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 07:35, 23 Oṣù Kẹrin 2023 (UTC)