DJ Xclusive
DJ Xclusive | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Rotimi Alakija |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kẹ̀wá 1980 St Austell England |
Occupation(s) | Dj, Àlágbásílé Òrín, Ólórín álágbásílè |
Years active | Ọdún 2003–títí dí òníì |
Labels | Empire Mates Entertainment |
Rotimi Alakija (tí á bí ní ọjó kérín-dín-lógún ósù kéwáà ọdún 1980), tí òpò mò sí́ DJ Xclusive, ó jé disc jockey Nàjíríà, Álágbéjádẹ ígbásílè ọrín átì olórìn álágbásílè.[1]
Ìbèrè Áyé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]England ní á tí bí Rotimi Alakija sí ówó àwón óbí Náìjíríà. Ní òdómódé, ó pádá sí Náìjíríà látì lépà èkó ní ílé èkó King's College, Ị̀lú Èkó. Rotimi Alakija pádà sí UK látì kó èkó Physics átì ìmò sáyénsì kómpútà ní Yúnífásítì Reading, ní bí tí ó tí gbá oyé ékò ílé-ìwè gígá. Ó tún pádà kó ékò ísúná ówó kómpútà ní Yúnífásítì Brunel, London.[2]
Ísé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]DJ Xclusive bérè ísé ójógbón disc jockey ní ódún 2003 nípà òpò ìsé sísé ní órísí ílé íjó álé, pélù Aura Mayfair, Penthouse, Funky Buddha átí Jalouse. Láàrín áwón ódún ísé rè, DJ Xclusive tí bá òrísírísí áwón òṣèrè bí Ne-Yo, Rihanna, Mario Winans, Brick and Lace, Nas àtí Fat Joe sísé pó.[3]
Ní ábálá tí ódún 2010 tí Nigeria Entertainment Awards, tí ó wáyé ní United States, DJ Xclusive gbá àmì éyé DJ tí ó dárájú ní áyé. ́ Á yán látì díjè DJ tí ó dárájù ní átúsè tí ódụ́n 2011 tí BEFFTA Awards. Ó tún sé fíìhàn ní House Party Big Brother ódún 2013.[4]
Ní ódún 2011, DJ Xclusive dí DJ ìlé Ílé fún CoolFM 96.9[5] ó sí dárápò mó Empire Mates Entertainment gégébí òsísé DJ tí Wizkid.[6]. DJ Xclusive sé ígbéjádè orín kán "I'm Xclusive" tí ólórín tí UK-Náìjíríà Mo Eazy.Àdàkọ:Cn
Ígbésí áyé áráéní
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dj Xclusive fé Tinuke Ogundero ní ódún 2015.[7][8] Ótún jé ábúrò si ólówó Náìjíríà Folorunsho Alakija.[9]
Áwón Ísé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Áwó kán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- "Pangolo" (pèlú Timaya)[10]
- "Ibebe" (pèlú Olamide) (2013)
- "Gal bad" (pèlú D'Prince and Wizkid) (2014)
- "Jeje" (pèlú Wizkid (2014)
- "Fatasi" (pèlú Terry G) (2014)
- "Tonight" (pèlúBanky W and Niyola) (2014)
- "Shaba" (pèlú Kcee and Patoranking) (2014)
- "Dami Si" (pèlú Lil Kesh and CDQ) (2015)
- "Oyoyo" (pèlú Burna Boy) (2016)
- "Sharwama" (pèlú Masterkraft) (2016)
- "Pose" (pèlú Tiwa Savage)(2017)
- Gbomo Gbomo (pèlú Zlatan Ibile)(2019)
- "Mad O" (2020)
- "Buga" (pèlú T-Classic) (2020)
- "Sweet 16" (pèlú Soft)) (2020)
- "Pariwo" (pèlú Dotman)(2020)
Ísé áwórán fídíò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]|style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | N/A
Ódún | Ákólé | Ólúdárí Ísé | Átókásí |
---|---|---|---|
2016 | Cash Only | [11] |
Ákópó Áwó Órín
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Empire Mates State of Mind (2012)
- According To X (2015)
Wó éléyí náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Átókásì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Watch: "Love" By DJ Xclusive". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-01-11. Archived from the original on 2022-03-02. Retrieved 2022-03-02.
- ↑ Afolasade, Samagbeyi (2020-09-04). "DJ XCLUSIVE WELCOMES NEW BABY". News Central TV | Latest Breaking News Across Africa, Daily News in Nigeria, South Africa, Ghana, Kenya and Egypt Today. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-03-02. Retrieved 2022-03-02.
- ↑ "Chillin DJ Xclusive". genevieveng.com. Archived from the original on 11 May 2012. Retrieved 1 April 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "DJ Xclusive to "Bring the House Down" at the Big Brother Africa: The Chase Finale Party". 20 August 2013.
- ↑ "DJ Xclusive Takes Residence in Lagos". questionmarkmag.com. Retrieved 1 April 2012.
- ↑ "DJ Xclusive joins EME". Bellanaija.com. 14 November 2011. Retrieved 1 April 2012.
- ↑ "BN Celebrity Weddings: Rotimi "DJ Xclusive" Alakija & Tinuke Ogundero Wedding". BellaNaija. https://www.bellanaija.com/2015/10/tbt-bn-celebrity-weddings-dj-xclusive-tinukes-wedding/.
- ↑ Tofatati Ige (7 November 2015). "I don't like talking about my marriage". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2015/11/i-dont-like-talking-about-my-marriage-dj-xclusive/.
- ↑ Akan, Joey (9 March 2014). ""I'm Not Folorunsho Alakija's Son" – DJ Xclusive Denies Report". Retrieved 29 January 2015.
- ↑ "VIDEO: DJ Xclusive – Pangolo ft. Timaya". Notjustok. 11 December 2013. Archived from the original on 15 December 2013. Retrieved 18 December 2013.
- ↑ "DJ Xclusive Sarkodie, Banky W, Cassper Nyovest, Anatii go hard in 'Cash only' video". Pulse.com.gh. David Mawuli. 25 September 2015. Retrieved 10 February 2016.
Íjápó Ítá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Áàyè áyélújárá òsìsé Dj Xclusive Archived 2022-01-10 at the Wayback Machine.
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Pages with citations using unsupported parameters
- Articles with short description
- Short description is different from Wikidata
- Webarchive template wayback links
- Ólórin édè Yoruba
- Ólóriñ Yórùbà
- Áwón DJ Hip Hop Náìjíríà
- Àwọn ènìyàn alààyè
- King's College, Lagos alumni
- Eníyàn Géèsì Írándírán Yórúbà
- Áláwódùdù DJ Britain
- Alumni of the University of Reading
- Alumni of Brunel University London
- Alakija Family
- 21st-century British musicians
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1980
- Eniyan Gèésí ní Ìrán Nàíjíríà