Ọ̀rọ̀:Sikọlashipu ti Chevening
Àkíyèsí àti ìkìlọ̀
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]@Taoheedah, mo kí ọ kú iṣẹ́ takuntakun. Mo fẹ́ fi akókò yí sọ fún ọ kí o ma ṣe akíyèsí òngbifọ̀ àwọn àyọkà rẹ dára dára kí o sì ma yẹ àwọn àyọkà èyíkéyí tí o bá fẹ́ ṣ'àpilẹ̀kọ rẹ̀ wò kíníkíní kí o tó ṣe atẹ̀jáde rẹ̀ sórí Yorùbá Wikipedia. Àyọkà tí o kọ yí, ṣé ó b'ójúmu? Kódà, kò ṣeé kà rárá bí ó ti wulẹ̀ kí ó mọ. Gbìyànjú kí o ṣàtúnṣe rẹ̀ kí ó lè dára jù báyìí lọ. Mo fẹ́ kí o mọ̀ wípé Wikipedia èdè Yorùbá tí kọjá ibi tí irúfẹ́ àwọn àyọkà báwọ̀nyí lè dúró sí. Bí o kò bá gbé ìgbésẹ̀ lọ́nà àti tún-n ṣe, ó ṣeéṣe kí á gbé fún píparẹ́ láìpẹ́. Ire oooAgbalagba (ọ̀rọ̀) 21:01, 16 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
- Akiyesi pataki: @Agbalagba, Mi o ki ọ ku iṣẹ takun takun. Oya mi lẹnu pe lẹyin igbiyanju lati tun ayọka (Chevening Sikọlashipu) ṣè, mo ri pe ati fagile! Eyi to wa buruju ni ibani lorukọ jẹ lori lilo irinṣẹ Goggle Translation ti ko ri bẹ. Mo gbọ Yoruba dara dara mo si kọ ni ile ẹkọ.
Going forward, I would appreciate if specific correction are given in subsequent notice as I could not depher what you were trying to point out. Rather than seeking to discredit my contributions to the Yoruba Wikipedia. I am always reachable and open to learning on the page. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 16:26, 4 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)
Text source
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]The page is now linked to its Wikidata item with seven other WP languages. Was the Yoruba text largely or entirely translated from any of those? The source doesn't appear in an edit summary of previous versions (Ìtàn àtúnyẹ̀wò), so if it's another WP version, this needs to be credited here on the Talk page. Deborahjay (ọ̀rọ̀) 12:44, 21 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
- It was translated from its English Wikipedia Version (Chevening Scholarship) @Deborahjay Taoheedah (ọ̀rọ̀) 07:05, 23 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
Àyọkà contains a translation of « Chevening Scholarship » from en.wikipedia. |