Ọ̀rọ̀ oníṣe:Zeemahgan

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ẹkáàbọ̀!

Ẹpẹ̀lẹ́ o, Zeemahgan,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:

Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! T CellsTalk 14:17, 24 Oṣù Kẹrin 2019 (UTC)Reply[ìdáhùn]

Wikiversity Yoruba Project[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ku ojo, mo fẹ pẹ ọ lati darapo mo iranlowo idagbasoke Wikiversity Yoruba bi ọ ṣe duro lati jẹ ki ọ ṣee ṣe fun Wikipedia Yoruba darapo mo ise yi ko le ni aseyori. Fun alaye siwaju beere lọwọ mi ni oju-iwe oro mi tabi lo si oju-ewe ibeere fun ede titun ni ori Meta-Wiki.Tbiw (ọ̀rọ̀) 21:33, 5 Oṣù Kẹ̀sán 2020 (UTC)Reply[ìdáhùn]

Àkíyèsí pàtàkì[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹ kú iṣẹ́ Oníṣẹ́:Zeemaghan, a dúpẹ́ fún akitiyan yín lórí iṣẹ́ yín sí orí ìkanì Yorùbá WP. Amọ́, mo fẹ́ pe yin sí àkíyèsí nípa àyọkà Noimot Salako-Oyedele tí ẹ ṣẹ̀ṣẹ̀ da sílẹ̀, kí ẹ ṣe àtúnṣe tí ó yẹ lórí rẹ̀ nítorí wípé àyọkà yí kò tó nkan, ati wípé mo tún fẹ́ mọ ọ̀nà tí mo lè gbà láti fi ran yín lọ́wọ́ láti ní ìmọ̀ kíkún nípa bí a ṣe ń ṣe àtúnṣe sí àyọkà siwájú si. Bí ẹ bá sì nílò ìrànwọ́ mi, ẹ lè kan sì mi fún ìrànlọ́wọ́ tí ẹ bá fẹ́. Ẹ ṣeun púpAgbalagba (ọ̀rọ̀) 17:20, 30 Oṣù Kẹta 2021 (UTC)Reply[ìdáhùn]