Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Tinúbu
Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Tinubu (tí a n pe ni Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Òmìnira tẹ́lẹ̀ rí), jẹ ọwọn manigbagbe ti o wa ni opopona gbooro (Broad Street), ni Erekusu Eko (Lagos Island), ni Ipinle Eko, ni orilẹ-ede Naijiria. [1] Ni igba kan ri, Ita Tinubu ni a npe ni irati Iyaafin Efunroye Tinubu [2] ti o je oniṣowo ẹrú ati gbajugbaja oniṣowo, ki o to di pe a yi orukọ rẹ pada si Ọ̀wọ́n Gbọ̀gàn Ominira lati owo awon oludari eto iṣejọba ara ẹni akoko ni Orilẹ-ede Naijiria, leyin eyi ni a tun wa yi oruko re pada si Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Tinubu. [3]
Àgbékalẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gbọ̀ngàn yii je onigun-mẹrin ti a fi irin se odi yii kaakiri, o si ni orisun omi meji ti o nfan omi si awon ododo ati awon igi ilẹ̀ olóoru ti o wa ninu rẹ̀. Ère Iyaafin Tinubu ti o ga to iwon eniyan wa ninu Gbọ̀ngàn yii o si duro lori orori kan. [3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Juliet Umeh. "Tourism: Maximising potential of Tinubu Square, Lagos". Archived from the original on 2016-04-02. https://web.archive.org/web/20160402053526/http://nationalmirroronline.net/new/tourism-maximising-potential-of-tinubu-square-lagos/.
- ↑ Ọladipọ Yemitan (1987). Madame Tinubu: Merchant and King-maker. University Press. https://books.google.com/books?id=iPIJAQAAIAAJ.
- ↑ 3.0 3.1 Seun Akioye. "Tinubu Square: A befitting memorial to an Amazon". http://thenationonlineng.net/tinubu-square-befitting-memorial-amazon/.