Rilwan Akinolú
Rilwan Akiolu | |
---|---|
Rilwan Akiolu in 2006 | |
Reign | 24 May 2003 – present |
Coronation | 9 August 2003 |
Predecessor | Adeyinka Oyekan |
Born | 29 Oṣù Kẹ̀wá 1943 Lagos, British Nigeria |
Religion | Islam |
Ọba Rilwan Babátúndé Oṣùọlálẹ́ Àrẹ̀mú Akiolú (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1943) ni Ọba ìlú Èkó àti alága gbogbo ọba aládé tó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó. Akiolú gorí ìtẹ́ ọba ìlú Èkó ni ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹjọ odun 2003. Ọba Adéyínká Oyékàn ló jọba, tí ó sìn wàjà kí Akiolú tó gorí ìtẹ́.[1]
Ìgbé-ayé èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọba Akiolú lọ sí ilé ìwé Ansar-Ud-Deen College, ní Surulere, ìpínlẹ̀ Èkó lọ́dún 1961-1965, kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin, (Bachelor of Laws degree, (LL.B) ní Ifáfitì ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó, the University of Lagos ní Akoka, receiving his Bachelor of Laws degree (LL.B)[2]
Ìfinijoyè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ kẹta-lé-lọ́gbọ̀n oṣù kàrún-ún ọdún 2003, a yan Akiolu nípasẹ̀ àwọn afọbajẹ ti ìjọba ìbílẹ̀ Èkó tí ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ọba ọ̀kàn-lè-lógún ti Èkó; ọjọ́ kejì ni wọ́n fi adé dé e lórí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹjọ ọdún 2003. Ó ti wà ní ipò yìí láti oṣù kárùn-ún ọdún 2003, nígbà tí ó tẹlẹ̀ Ọba Adeyinka Oyekan.[3]
Ìdílé Ọba Akinsemoyin ti ìlú Èkó ti takò ifìjọba Ọba Akiolu ní ilé ẹjọ́, tí wọ́n ń kòrira, láàrín àwọn mìíràn, wípé wọ́n kò gba ìran wọn lọ́wọ́ lórí ìtẹ́. [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Elegbede, Adewunmi. "Kingdoms of Nigeria: The Nigerian Database of Rulers, Kings, Kingdoms, Political and Traditional Leaders". Kingdoms of Nigeria, The Nigerian Database of Rulers, Kings, Kingdoms, Political and Traditional Leaders. Retrieved 2019-11-30.
- ↑ "Oba Rilwan Akiolu Archives - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2019-11-30.
- ↑ "Oba of Lagos". Kingdoms of Nigeria. Archived from the original on March 4, 2016. Retrieved June 11, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Oba Akiolu’s Claim Being Challenged By Another Royal Family". Archived from the original on 2019-06-17. Retrieved 2017-08-05. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)