Ọjà Oṣòdì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oshodi market lagos

Ọjà Oṣòdì jẹ́ Ọjà tí ó wà ní apá kan ní ìlú Oṣòdì ní àárín ìgboro located in Oshodi, a suburb of Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọjà tí ó tobi gidi láàrín Èkó. Nígbà kan rí, ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó sọ wípé àwọn ìwà búburú oríṣiríṣi bí ìlọ́ni-lọ́wọ́ gbà, olè jíjà, àpò rírẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ìdí nìyí tí ìjọba fi gbé ìgbésíẹ̀ bí wọ́n ṣe da ọjà náà wó. ni ó sòódó sí inú ọjà náà wó.[1][2]. Ìjọba tún ọjà náà kọ́ ní oṣù Kínni ọdún 2016[3].

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Google Books. "Urban and regional planning in Nigeria". Nigeria Institute of Town Planner Lagos Chapter. Retrieved 11 January 2016. 
  2. A J Kumuyi. "Oshodi+market"&dq="Oshodi+market"&hl=en&sa=X&redir_esc=y "Oshodi market". Nigerian Institute of Social and Economic Research. Retrieved 10 January 2016. 
  3. "Oshodi Market demolition: One man's policy is another man's pain - Ventures Africa" (in en-US). Ventures Africa. http://venturesafrica.com/features/oshodi-market-demolition-one-mans-policy-is-another-mans-pain/.