Jump to content

1979 Lagos State gubernatorial election

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Idibo gomina ipinle Eko lodun 1979 waye ni ojo kejidinlogbon osu keje odun 1979. Oludije UPN Lateef Jakande lo jawe olubori lehin kika ibo naa. [1] [2]

Lateef Jakande to n soju UPN lo jawe olubori ninu ibo naa. Idibo ti o waye ni ojo meji din lo gbon Oṣu Keje 1979. [3] [4]

  1. Joseph, Richard A. (1981). "The Ethnic Trap: Notes on the Nigerian Campaign and Elections, 1978-79". Issue: A Journal of Opinion (Cambridge University Press) 11 (1/2): 17–23. JSTOR 1166229. 
  2. Okpu, Ugbana (1985). "Inter-Party Political Relations in Nigeria 1979-1983". Africa Spectrum (Sage Publications, Ltd.) 20 (2): 191–209. JSTOR 40174204. 
  3. Empty citation (help) https://www.worldstatesmen.org/Nigeria_federal_states.htm
  4. Nigeria: The 1979 Elections. https://rainbownigeria.com/2020/09/19/nigeria-second-republic-governors/ Archived 2021-04-28 at the Wayback Machine.