2020 African Sahel floods
Ìrísí
2020 African Sahel floods jẹ́ àwọn ìkún omi ńlá tí ó dé bá àwọn orílẹ̀ èdè ní ìwọ̀ oòrùn, ìlà oòrùn àti àárín Áfríkà ní àárín oṣù kẹjọ sí ìkẹ́sán ọdún 2020 nítorí òjò líle. Àwọn ènìyàn tí ó tó ọ̀kẹ́ mèjì-dín-ní-ogójì(760,000) ni ó ní ìmò lára ipa òjò náà ní àwọn orílẹ̀ èdè bi Burkina Faso, Cameroon, Chad, Congo Republic, Ghana, Mali, Niger, Nigeria, Sudan, Senegal, àti Tunisia , àwọn tí ó sì pa tó ìlọ́po ọgọ́rùn-ún ènìyàn.[1][2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Celestial, Julie (September 12, 2020). "Exceptional rainfall and record floods hit African Sahel". The Watchers. https://watchers.news/2020/09/12/extreme-rainfall-record-floods-african-sahel-2020/.
- ↑ "Senegal – State of Emergency After Deadly Floods". Floodlist. 7 September 2020. http://floodlist.com/africa/senegal-state-of-emergency-after-deadly-floods.