Jump to content

419 (novel)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
419
Fáìlì:419 (Will Ferguson novel - cover art).jpg
First edition cover
Olùkọ̀wéWill Ferguson
CountryCanada
LanguageEnglish
Genrefiction
PublisherPenguin Canada
Publication date
2012
Media typePrint (hardback & paperback)
ISBNÀdàkọ:ISBNT
OCLC863129982

419 ni ìwé àkàgbádùn tí ọmọ orílẹ̀-èdè Canada tí ó ń jẹ́ Will Ferguson kọ tí ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wé Penguin Canada ní ọdún 2012. Ìwé yí ni ó gba amì-ẹ̀yẹ Scotiabank Giller Prize ní ọdún 2012.[1] Àkòrí ìwé yí ni ó da lórí ìwà ọ̀daràn alọ́nilọ́wọ́gbà tí ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń gbógun tì. Ìwé yí ni ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀dá ìtàn kan tí ó ń jẹ́ Albert tí ó sì jẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Calgary. Albert pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ nínú ìjàmbá ọkọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n Lù ú ní jìbìtì owó tí òun ati ẹbí rẹ̀ sì ti di ẹdun arinlẹ̀. Lẹ́yìn tí ó pàdánù ẹ̀mí rẹ̀, ọmọ rẹ̀ obìrin wá sí ìlú Èkó. Akòrí ìwé yí ni ó da lé bí ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe ń gbógun ti ìwà jìbìtì ati ilọ́nilọ́wọ́-gbà àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìṣẹ̀lẹ̀ inú ìwé yí bẹ̀rẹ̀ níbi tí Albert tí ó fìgbà lan jẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Calgary tí ó kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ lẹ́yìn tí àwọn alọ́nilọ́wọ́-gbà tí wọ́n sì sọ òun ati ẹbí rẹ̀ di ẹdun arinlẹ̀. Lẹ́yìn ikú rẹ̀, ọmọ rẹ̀ obìnrin kan ṣoṣo tí ó bí wá sí ìlú Èkó láti wá lépa àwọn tí wọ́n lu bàbá rẹ̀ ní jìbìtì kí ó sì fi wọ́n jófin.[2] Irúfẹ́ ìwé àpilẹ̀kọ tí wọ́n Mọ Ferguson mọ́ ni kíkọ ìwé apanilẹ́rìín. [1]

Àríwísí nípa ìwé náà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn oríṣiríṣi ònkàwé ni wọ́n sọ̀rọ̀ nípa ìwé náà dára dara. ÀjọThe Globe and Mail oe ìwé náà ní "Riveting. Provocative."[3] Àjọ Toronto Star náà pe ìwé náà ní "a persuasive work of fiction based on a very original premise."[4]

Àwọn itọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Giller Prize


Àdàkọ:2010s-crime-novel-stub Àdàkọ:Canada-novel-stub