AKBC
Ìrísí
Akwa Ibom State Broadcasting Corporation (kikuru AKBC) UHF channel 45, jẹ́ ilé-iṣẹ́ tẹlifísíọ̀nù ti ìjọba ní Uyo, Akwa Ibom.[1] Akwa Ibom Broadcasting Corporation jẹ́ dídá sílẹ̀ ní Ọjọ́ 4 Oṣù Kẹrin ọdún 1988 àti pé ó jẹ́ àkọ́kọ́ àti ìbùdó tẹlifíṣíọ̀nù agbègbè nìkan. AKBC pese tẹlifísíọ̀nù méjèèjì àti àwọn iṣẹ́ rédíò.[2] Ó ń darí ní 90.528MHZ. AKBC tẹlifísíọ̀nù tàn káàkiri láti Ntak Inyang.[3]
Ọdún 1991 ní gómìnà Ipinle Akwa Ibom, ìyẹn Idongesit ṣí ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn náà sílẹ̀.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Otu, Mercy (2006) (in en). Broadcasting in Nigeria: Akwa Ibom Broadcasting Corporation Experience. MEF (Nigeria) Limited. ISBN 978-978-012-058-0. https://books.google.com/books?id=ak64AAAAIAAJ&q=akbc.
- ↑ "Channels Info". nbc.gov.ng. Archived from the original on 27 August 2017. Retrieved 27 August 2017.
- ↑ Otu, Mercy (2006) (in en). Broadcasting in Nigeria: Akwa Ibom Broadcasting Corporation Experience. MEF (Nigeria) Limited. ISBN 978-978-012-058-0. https://books.google.com/books?id=ak64AAAAIAAJ&q=akbc.