Abdullahi Muhammad Kwadon
Ìrísí
Abdullahi Muhammad Kwadon je olóṣèlú ati olùkọ́ ọmọ Nàìjíríà ti a bi ni ọdún 1940s ni Kwadon, ni ìjọba ìbílè Yamaltu Deba, ìpínlẹ̀ Gombe, Nigeria . [1] O jẹ olori akọkọ ti Ile-igbimọ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Gombe ni ọdun 1999 ati pe o tun ṣiṣẹ gẹgẹbi alákòóso pẹlu Ìgbìmò Iṣẹ Ijọba Àgbègbè. Abdullahi Muhammad Kwadon jáde laye ni eni odun marundinlogorin. Aya mẹ́rin, ọmọ ọgbọ̀n [30], àti ọ̀pọ̀ ọmọ ọmọ ló kú. [2] [3]