Abdullahi Umar Ganduje

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abdullahi Umar Ganduje

Abdullahi Umar
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kánò
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2015
AsíwájúRabiu Kwankwaso
Deputy Governor of Ìpínlẹ̀ Kánò
In office
29 May 1999 – 29 May 2003
Arọ́pòMagaji Abdullahi
In office
29 May 2011 – 29 May 2015
AsíwájúAbdullahi Tijjani Gwarzo
Arọ́pòProf. Hafizu Abubakar
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kejìlá 1949 (1949-12-25) (ọmọ ọdún 74)
Ganduje, Dawakin Tofa, Ìpínlẹ̀ Kánò
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress (APC)
(Àwọn) olólùfẹ́Hafsat Umar
ResidenceKano, Nàìjíríà
Alma materAhmadu Bello University
Bayero University Kano
University of Ibadan
OccupationPolitician
ProfessionAdministrator
Websiteganduje.com.ng

Abdullahi Umar Ganduje, OFR tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1945 (25 December 1945) jẹ́ olóṣèlú àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kánò lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ọdún 2015.[1] Kí ó tó di Gómìnà, òun ni igbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano, lọ́dún 1999 sí 2003 àti 2011 sí 2015.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Nnochiri, Ikechukwu (2020-01-20). "Supreme Court upholds Ganduje's election, dismisses Yusuf's appeal". Vanguard News. Retrieved 2020-03-09.