Rabiu Kwankwaso
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Rabiu Musa Kwankwaso)
Rabiu Kwankwaso FNSE | |
---|---|
Governor, Kano State, Nigeria | |
In office 29 May 1999 – 29 May 2003 | |
Asíwájú | Colonel Aminu Isa Kontagora |
Arọ́pò | Ibrahim Shekarau |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1956 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Salamatu Rabiu Musa |
Àwọn ọmọ | 6 |
Rabi'u Musa Kwankwaso FNSE (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀jilelogun oṣù kewa ọdún 1956) jẹ́ gbajúgbajà olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Kano lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni gomina Ipinle Kano tele ri.[1][2]
Ni odún 2022,ni won yan Rabiu Kwankwaso gẹ́gẹ́ bi olùdíje fun aare orílẹ̀ èdè Naijiria ti odun 2023 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú New Nigeria People's Party.[3][4][5][3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "PHOTO: Kwankwaso sparkles in 'unusual' outfit". Daily Trust. June 21, 2022. Retrieved June 22, 2022.
- ↑ "Peter Obi and Rabiu Kwankwaso ticket: 'We dey discuss how to run togeda'". BBC News Pidgin. June 18, 2022. Retrieved June 22, 2022.
- ↑ 3.0 3.1 "Kwankwaso won’t serve as Peter Obi’s running mate - NNPP". Vanguard News. June 19, 2022. Retrieved June 22, 2022.
- ↑ "NNPP debunks rumours of Kwankwaso becoming Obi running mate". Punch Newspapers. June 19, 2022. Retrieved June 22, 2022.
- ↑ Ogala, George (June 8, 2022). "Ex-Kano Governor, Kwankwaso, emerges NNPP presidential flag bearer". Premium Times Nigeria - Premium Times - Nigeria's leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria. Retrieved June 22, 2022.