Abraham Adesanya
Ìrísí
Chief Abraham Adesanya | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Abraham Aderibigbe Adesanya 24 July 1922 Ijebu Igbo, Southern Region, British Nigeria (now in Ogun State, Nigeria) |
Aláìsí | 27 April 2008 | (ọmọ ọdún 85)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Holborn College of Law |
Iṣẹ́ |
|
Political party | Action Group |
Olólùfẹ́ | Rosannah Arinola Adesanya |
Àwọn ọmọ |
|
Parents |
|
Olóyè Abraham Aderibigbe Adesanya /θj/ (24 July 1922 – 27 April 2008) fìgbà kan jé olóṣèlú, agbẹjọ́rò, ajìjàgbara ọmọ orílè-èdè Naijiria.[1]
Òun ni ọmọ gbagbúgbaja Oloye Ezekiel Adesanya (tí àwọn ènìyàn tún ń pè ní Baba Obu’keagbo), tó wà láyé ní sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún, tí ìyà rẹ̀ sì ń jẹ́ diya Adesanya. Ó fẹ́ arábìnrin Rosannah Arinola Adesanya, née Onafalujo, èyí tó kú lẹ́yìn ọdún kejì tí ọkọ rẹ̀ kù. Wọ́n jìjọ bí ọmọ mẹ́rin, àwọn ni: Adebayo Adesanya, Oluwasegunfunmi Adesanya, Modupeola Adesanya Adelaja àti Olufemi Adesanya. Wọ́n ní àwọn ọmọ-ọmọ mẹ́wàá.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Obasanjo: How Abraham Adesanya rejected me thrice". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-02. Retrieved 2022-03-09.