Achistrum
Ìrísí
Achistrum | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | Achistrum
|
Achistrum jẹ́ ìdílé kòkúmbà òkún tí a kò rí mọ́ ṣùgbọ́n tí a ti rí tẹ́lẹ́ ni Poland ní ìgbà Triassic, àti ní United States Ìgbà Eléèédú.[1] Àwọn ẹ́yà tí ó wà nínú rẹ̀ ni Achistrum nicholsoni àti Achistrum ludwigi.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Triassic Holothurian Sclerites from Tatra Mountains Krystyna Zawidzka.