Adam A Zango

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adam a zango
Ọjọ́ìbíAdamu Abdullahi Zango
1 Oṣù Kẹjọ 1985 (1985-08-01) (ọmọ ọdún 38)
Zangon Kataf, Kàdúná,
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Òṣèré orí-ìtàgé, Olùgbéré-jáde Ọ̀kọrin àti oníjó.
Net worth₦100million Naira
Olólùfẹ́Safiya chalawa
Àwọn ọmọHaidar A Zango
AwardsBest Actor

Adam A Zango tí wọ́n tún mọ̀ sí Gwaska, jẹ́ òṣèré,olùgbéré-jáde, adarí eré, olùkọ̀tàn, olórin ọmọ ẹ̀yà Hausa ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni wọ́n gbà wípé ó jẹ́ ẹni tó lààmì-laaka jùlọ ní agb Kannywood. Ní ọdún 2019, ó júwe ara rẹ̀ gègẹ́ bí ẹni tí ó nípa jùlọ ní ilẹ̀ Hausa. Púpọ̀ nínú àwọn adarí eré ní agba Kannyeood ni wọ́n ń gbóríyìn fún látàrí bí ó ṣe lè kópa dáradára ní inú ipa èyíkéyí tí wọ́n bá fún wípé kí ó ṣe. Adamu Zsngo ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí ti Ali Nuhu náà ní agbo àwọn òṣèré Kannywood. [1]

Ìgbà èwe àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Adam Abdullahi Zango ní inú oṣù Kẹwàá ọdún 1985, ní Agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Zango ní Ìpínlẹ̀ Kádúná. Babá rẹ̀ ni Mallam Abdullahi Adam. Zango kò lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga kankan, amọ́ ó lérò wípé ìkẹ́kọ̀ọ́ ju kí a kó ìwé-ẹ̀rí aọ́wọ́ lọ, amọ́ ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní àárín ọdún 1989–1995, tí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gurama ní àárí ọdún 1996–2001.Àdàkọ:Cn

Iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adam Zango ti bẹ̀rẹ̀ sí ń kọrín nígbà tí ó ti wà ní ilé-ẹ̀kọ́ girama . Òun náà ló ma ń ṣojú ilé-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní inú ìdíje eré ati orin ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ rẹ̀. Zango dara pọ̀ mọ́ Kanywood ní ọdún 2001gẹ́gẹ́ akọrin, amọ́ tí ó lo ànfaní yí láti bẹ̀rẹ̀ sí ń kópa nínú àeọn eré orí-ìtàgé gbogbo. Ó ti kópa nínú eré tí ó ti tó ọgọ́rùn ún ṣáájú kí ó tó di àgbà ọ̀jẹ̀ òṣèré ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti gba amì-ẹ̀yẹ Africa Movie Award in London, ní ìlú UK.

Bí ó ṣe lọ sí ẹ̀wọ̀n[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n fi Adam A. Zango sí ọgbà ẹ̀wọ̀n fún bí ó ṣe lu òfin ìkànìàn ní ti ọdún 2007 látàrí orin rẹ̀ tí ó gbé jáde lórí ètò ìkànìyàn tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ Bahaushiya.[2]

Ìtọrẹ Àánú rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní inú oṣù Kẹwàá ọdún 2019, Adam fún àwọn ọmọ aláìníyá ní iye tí ó tó 47 million láti lè jẹ́ kí wọ́n tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ wọn.[3]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Eré Ọdún
Ya Ya na ND
Yar Agadez 2011
Adamsi 2011
Addini ko Al 'Ada 2011
Adon Gari 2011
Ahlul Kitab 2011
Alkawari na 2011
Albashi (The Salary) 2002
Andamali 2013
Ango da Amarya ND
Artabu 2009
Aska Tara ND
Auren Tagwaye ND
Baban Sadik 2012
Babban Yaro 2011
Balaraba 2010
Basaja 2013
Bayan Rai 2014
Bita Zai Zai ND
Dajin So ND
Dan Almajiri ND
Dare 2015
Dijangala 2008
Duniya Budurwar Wawa ND
Dutsen Gulbi 2013
Farar Saka ND
Fataken Dare ND
Ga Duhu Ga Haske 2010
Ga Fili Ga Mai Doki ND
Gaba da Gabanta 2013
Gambiza ND
Gamdakatar ND
Gwamnati 2003
Gwanaye 2003
Gwaska 2016
Hadizalo ND
Hindu 2014
Hisabi 2017
Hubbi 2012
Ijaabaah ND
Jamila 2016
Kaddara Ko Fansa 2014
Kama da Wane 2014
Kare Jini ND
Kolo ND
Kundin Tsari ND
Laifin Dadi 2010
Larai ND
Madugu ND
Masu Aji ND
Mata ko Ya 2015
Matsayin So ND
Mazan Fama ND
Matsayin So ND
Mazan Fama 2015
Mukaddari ND
Murmushin Alkawari ND
Mutallab 2011
Nai Maka Rana ND
Namamajo ND
Nas 2013
Ni Da Ke Mun Dace 2013
Najeriya Da Nijar 2012
Nusaiba ND
Rabin Jiki 2011
Rai A Kwalba ND
Rai Dai 2012
Rawar Gani ND
Rintsin Kauna ND
Rumana 2017
Ruwan Ido ND
Ruwan Jakara ND
Sai Wata Rana 2010
Salma ND
Shahuda 2012
Siyayya Da Shakuwa 2014
Sayayyar Facebook 2013
Tarkon Kauna ND
Tsangaya ND
Ummi da Adnan 2011
Walijam 2010
Wata Rayuwa 2013
Ya Salam ND
Zanen Dutse ND
Zarar Bunu 2011
Zatona ND
Zeenat 2014
Zo Mu Zauna ND
Zulumi 2017

[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1 minute read (2018-05-06). "Brief history of Prince Adam A Zango and his collection of photos –". Gobirmob.com. Archived from the original on 2018-02-18. Retrieved 2019-09-04. 
  2. "Archived copy". Archived from the original on 24 February 2013. Retrieved 12 May 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. A Zango ya raba guraben karatu ga fadar sarkin zazzau Legit Hausa
  4. Flowalk (2017-03-25). "The Biography Of Adam A. Zango [Age, Life Profile & Net Worth]". 360post.wordpress.com. Archived from the original on 2019-05-12. Retrieved 2019-09-04. 

Ìtàkùn ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]