Adebayo Alonge

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
MNIM
Adebayo Alonge
Adebayo Alonge, 2019.
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànSamuel
Iléẹ̀kọ́ gígaKing's College, Lagos
(Senior School Certificate)
University of Ibadan
(Bachelor of Pharmacy)
Lagos Business School
(Master of Business Administration)
Yale School of Management
(Master of Advanced Management)
John F. Kennedy School of Government
(Master of Public Administration)
Graduate School of International Corporate Strategy
(International business)
Gbajúmọ̀ fúninvention of RxScanner
AwardsAwards in person from Barack Obama (ex-US president) and Justin Trudeau (prime minister of Canada)[citation needed]

Regional finalist, Hult Prize Global Case Competition

Young Innovator – YouWin!

Grand Winner & Digital Health Winner, Hello Tomorrow Global Challenge 2019

Winner, deep tech Award with a €100,000 prize, 2019

2018 China Award for Best deep tech Platform in the World[citation needed]

Global Social Venture Award (2016) from InnovateHealth, Yale

Mandela Washington Fellowship from the United States Department of State for outstanding contributions to business and entrepreneurship in Africa (2014)

Adekunle Ajasin Award for Academic Excellence in 2008

Adebayo Alonge jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó jẹ́ olóògùn àti oníṣòwò. Òun ló jáwé olúborí fún ìdíje tí ọdún 2019 ti Hello Tomorrow Global Deeptech Challenge, èyí tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí BNP Paribas Group Deep Tech Award. Ó gba àmì-èyẹ yìí látàri irinṣẹ́ kan tó lè ṣàwárí oògùn ẹbu tí ó ṣẹ̀dá. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùṣèdásílẹ̀ [1]RxAll Inc.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Fake pharmaceutical industry thrives in West Africa" (in en-gb). BBC News. 2020-07-13. https://www.bbc.com/news/world-africa-53387216. 
  2. "RxAll, Founded by Adebayo Alonge '16, Named Best Early-Stage Startup in Hello Tomorrow Global Challenge". Yale School of Management (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-21. Retrieved 2020-01-20.