Adebisi Balogun
Adebisi Balogun | |
---|---|
Ìgbákejì kàrún tí Federal University of Technology Akure | |
In office January 2007 – January 2012 | |
Asíwájú | Peter Adeniyi |
Arọ́pò | Emmanuel Adebayo Fashakin (acting) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Adebisi Mojeed Balogun 2 Oṣù Kẹjọ 1952 Ilé-Ifẹ̀, Southern Region, British Nigeria (bayi Ìpínlẹ̀ Osun, Naijiria) |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
(Àwọn) olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 3 |
Àwọn òbí | Adetunji Saka Balogun (bàbá) |
Alma mater | University of Ibadan |
Profession | Olùkọ́ |
Adebisi Mojeed Balogun (ọjọ́ìbí 2 oṣù kẹjọ odún 1952) jẹ ọmọ orílẹ-èdè Nàìjíríà onimọ ẹtọ-ògbìn biochemist, ọlukọni, onìwòsàn oúnjẹ, ọmowé atí òjògbón nípa oúnjẹ ẹ̀já, tí ọ ṣiṣẹ gẹ́gẹ́ bí ìgbákejì ọgá àgbà ilé ìwé gígá Federal University of Technology Akure láti January 2007 sí January 2012.[1][2][3]
Ìgbésí áyé ìbẹ̀rẹ̀ àtí ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Adebisi Balogun ní wọn bí ní ọjọ́ kéji oṣù kẹ́jọ odún 1952 ní Ilè Ifẹ̀, nígbà náà ní Southern Region, British Nigeria, sí Adetunji Saka atí Modelola Balogun (née Afilaka). Ó lọ sí Yunifásítì ìlú Ìbàdàn níbi tí ó tí gba ẹ̀kọ́ ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ní 1976, ọ̀gá nínú ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ní 1978 àti dókítà ìmọ̀ ọ.[4]
Ìṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lèyìn tí ọ gba doctorate degree ní 1982, ọ dị ẹ́lẹ́gbẹ́ ìwádì, Nigerian Institute of Oceanography and Marine research, Lagos, Nigeria láti 1982 sí 1983, ọ jẹ olùkọ ní University of Ibadan láti 1983 sí 1988, ọ gbé sí Federal University of Technology Akure ní 1988. Ọ dí òjògbón ní 1994, ọ jẹ Dean tí School of Agriculture and Agricultural Technology, FUTA láti 1997 sí 2001.[4] Ọ jẹ ọmọ ẹgbẹ́ tí Alàgbà tí FUTA láti 1988 sí 2012, ọmọ ẹgbẹ́ tí ìgbìmọ̀ ìjọba láti 1993, Ìgbìmọ̀ Ìwádì Olùkọ́, Ilé-ìwé tí Agriculture atí Agricultural Technology, alága Environmental Sanitation Committee, Ìgbimọ Ìdárayá, Ìgbìmọ̀ Àwọn ayẹyẹ Alága atí Ìgbákejì Alàkóso láti Odún 2007 sí 2012.[4][3]
Àwọn ìtọkásí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Former Vice Chancellor identifies poor governance as main problem of Universities". News Diary Online. 5 August 2022. Retrieved 19 October 2022.
- ↑ "Nigeria: Why Nigeria is Backwards in Technology -- Futa VC". All Africa. 23 February 2010. Retrieved 19 October 2022.
- ↑ 3.0 3.1 "Previous Vice-Chancellors | FEDERAL UNIVERSITY OF TECHNOLOGY AKURE". www.futa.edu.ng. Retrieved 17 October 2022.
- ↑ 4.0 4.1 4.2 "BALOGUN ADEBISI MOJEED | FEDERAL UNIVERSITY OF TECHNOLOGY AKURE" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 19 October 2022.