Adefunmilayo Tejuosho

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Hon.
Funmi Tejuosho
Ọjọ́ìbíAdefunmilayo Smith
25 Oṣù Kẹta 1965 (1965-03-25) (ọmọ ọdún 59)
ìpínlè Èkó, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Orúkọ mírànOloori Adefunmilayo Tejuosho
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́1997 – present
Political partyẸgbẹ́ òsèlú All Progressives Congress
Olólùfẹ́Omoba Kayode Tejuosho
Àwọn ọmọ4

Adefunmilayo Tejuosho (orúko abiso rè ni Smith) tí a bi ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù Kàrún ọdun 1965 jé òtòkùlú olósèlú ni Nàìjirià, o tun jé asoju agbegbe Mushin ní house of Assembly ìpinlè Eko, oun ni alaga house of assembly Eko ti o un rí si ètò owó.

Àárò Aye àti Èkó rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi Tejuosho ni ipinle Eko si idile Ademola Smith,[1] O lo ilé-ìwé primari ti Yunifásitì Ìlú Eko, o lo ilé-ìwé Queens College fún ìwé Sekondiri, Eko o pari ìwé Sekondiri rè ni West Virginia, léyìn ìwé rè, o tèsíwájú láti gba àmì-èye ninú ìmò Biology ni yunifásitì ti West Virginia.[2] O pada gba àmì-èye ninú imo ofin ni Yunifásitì ti Buckingham. Tenuous gba àmì-èye Ph.D nínú ìmò ofin láti Yunifásitì ti ìlú Eko.[3]

Isé rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nigba isé agubaniro rè, o sise ni ilé-ìwé Queens College ti o ti jáde. Ni odun 2003, a yan sip láti soju house of Assembly ìpinlè Eko, nigba to wa nipo náà, o mu aba ofin wa lati dojuko oko nina iyawo ati iyawo nina oko. Àbá náà pada di ofin.

Ìdílé rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O fe Omoba Kayode Tejuosho ti idile ade Tejuosho ìpínlè Ogun , Nàìjíríà.[4] awon mejeji bi omo merin.

Àwon Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Oladesu, Emmanuel (2014-05-12). "Who is next Lagos deputy governor?". The Nation Newspaper. Retrieved 2022-05-30. 
  2. "Funmi Tejuosho" Check |url= value (help). Hyperleap. 1965-03-25. Retrieved 2022-05-30. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "HON. FUNMI TEJUOSO LOSES FATHER". Encomium Magazine. 2022-05-30. Retrieved 2022-05-30. 
  4. "Hon. Funmi Tejuosho enumerates what life has taught her at 49". Encomium Magazine. 2014-03-29. Retrieved 2022-05-30.