Adenike Oladosu
Adenike Oladosu | |
---|---|
Oladosu in 2020 | |
Ọjọ́ìbí | Adenike Titilope Oladosu 30 Oṣù Kẹ̀sán 1994 Abuja, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Titilope |
Ẹ̀kọ́ | University of Agriculture, Makurdi |
Iṣẹ́ | Activist And Ecofeminist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2018–present |
Gbajúmọ̀ fún | Climate activism |
Awards | 22 diverse voices to follow on Twitter this Earth Day by Amnesty International.15 ambassador of the African youth climate hub. |
Adenike Oladosu ( tí wọ́n bí ní 1994[1]) jẹ́ olùgbèjà fún agbègbè àláìléwu fún àwọn ènìyàn àwùjọ, ó sì tún jẹ́ olùgbèrò fún ìdaṣẹ́sílè ilé-ẹ̀kọ́ fún ojú-ọjọ́ tó tẹ́rùn ní oríléédè Nàìjíríà[2][3][4]. Ó tún ṣàfihàn ìṣe ojú-ọjọ́ àìléwu ní àwọn àpèjọ ilẹ̀ òkèèrè tí UN Climate Change Conference, World Economic Forum, àti Elevate Festival nió GRaz-Austria.[5]
Ní oṣù kejìlá, ọdún 2019, Oladosu kópa nínú ìpàdé COP25 ní Spain gẹ́gẹ́ bí i aṣojú àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà níbi tí sọ̀rọ̀ tó mú àwọn ènìyàn lọ́kàn nípa àyípadà ojú-ọjọ́ níilẹ̀ Áfríkà àti bí ó ṣe yí àwọn ayé padà.[6][7]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oladosu jẹ́ ọmọ ògbómọ̀ṣọ́ láti ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà.[8] Ó kàwé ní Government Secondary School, Gwagwalada, Abuja. Ó sì tún tẹ̀ síwájú ní ilé-ẹ̀kọ́ Federal University of Agriculture, Markurdi níbi tí ó ti gba ìpò iyì àkókọ́ nínú èkọ́ Ọ̀rọ̀-ajé ajẹmọ́gbìn.[9][8][10]
Ní ọdún 2019, wọ́n yàn án fún ìpàdé àkọ́kọ́ ti UN lórí ọ̀rọ̀ nípa ojú-ọjọ́ ní New York. Pẹ̀lú ìdánimọ̀ UNICEF gẹ́gẹ́ bíi ọ̀dọ́ tó ń mú ìyípadà dé bá ìlú, ó ń darí àjọ kan tí wọ́n ń pè ní ILeadClimate.
Ní 2019, wọ́n yàn án fún ìpàdé UN Youth Climate àkọ́kọ́ tó wáyé ní New York. Kò ṣàjèèjì sí ìgbìmọ̀ UNICEF Nàìjíríà gẹ́gé bí i ọ̀dọ́ aṣèyàtọ̀, ó ń darí ìdàgbàsókè ìbílẹ̀ tí ń ṣe ILeadClimate, tó ń ṣègbè fún ìràpadà Lake Chad àti ìkópa àwọn ọ̀dọ́ nínú ìdájọ́agbègbè àláìléwu fún àwọn ènìyàn àwùjọ nípa ẹ̀kọ́.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Tsanni, Abdullahi (2019-06-11). "My fight for climate action has just begun – Adenike Oladosu". African Newspage (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-01-27.
- ↑ Simire, Michael (2019-09-19). "Six Nigerian youth activists to attend UN Climate Summit". EnviroNews Nigeria - (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-01-26.
- ↑ Watts, Jonathan (2019-09-19). "'The crisis is already here': young strikers facing climate apartheid" (in en-GB). The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/environment/2019/sep/19/the-crisis-is-already-here-young-strikers-facing-climate-apartheid.
- ↑ McCarthy, Joe. "12 Female Climate Activists Who Are Saving the Planet". Retrieved 22 January 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Oladosu Adenike Titilope". YBCA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-01.
- ↑ Breeze, Nick. "Youth strikers march for climate justice". The Ecologist. Archived from the original on 26 January 2020. Retrieved 22 January 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ ""We need climate action," urge Nigerian children". CNN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-14. Retrieved 2021-01-21.
- ↑ 8.0 8.1 "Meet Adenike Oladosu, A Climate Justice Activist And Eco-reporter" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-08.
- ↑ Adebote, ‘Seyifunmi (2019-09-19). "Six Nigerian youth activists to attend UN Climate Summit". EnviroNews Nigeria - (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-01-26.
- ↑ Tsanni, Abdullahi (2019-06-11). "My fight for climate action has just begun – Adenike Oladosu". African Newspage (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-01-27.