Jump to content

Adeoye Adisa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Adeoye Adisa jẹ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati aṣòfin pẹ̀lú agbẹjọ́rò láti ìpínlè Oyo. O di olóògbé ni ọjọ kerindinlogun oṣù kọkànlá ni ọdún 2015. Síwájú ki o to di olóògbé o ṣiṣẹ gẹgẹbi Komisona ati minisita.[1]