Adunni Bankole

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adunni Bankole
Ọjọ́ìbíMarch 1959
Abeokuta, Ogun State, Nigeria
Aláìsí3 January 2015
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànYeye Mokun of Owu kingdom[1]
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Businesswoman
Olólùfẹ́Alani Bankole[2][3]
Àwọn olùbátanDimeji Bankole (Step son)[4]

Adunni Bankole (Oṣù Kẹ́tá, ọdún 1959 - ọjọ́ Kẹ́tá Oṣu Kini ọdún 2015) jẹ ólùdarí àwùjọ ni Nàijíríà atí óbinrín oníṣòwò. Ó jẹ́ Yèyé Mokun tí ijọ́bá Owu, ìlú kan ni Abẹ́òkúta, olú-ìlú ti Ìpínlẹ̀ Ògùn, gúusù ìwọ̀-óòrùn Nàijíríà .

Ìgbésí ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi ní Oṣù Kẹ́tá ọdún 1959 ni Owu ti Abẹ́òkúta ni Ìpínlẹ̀ Ògùn, gúusù ìwọ̀-óòrùn Nàijíríà . Ó ṣe ìgbéyàwó pẹlú olóṣèlú ijọ́bá olómìníraá kejí, Olóyè Alani Bankole tí ó jẹ́ baba fún agbọ̀rọ̀sọ tẹ́lẹ̀ tí ilé àwọn aṣojú, ọlọla Dimeji Bankole .

Iku[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O kú nípa ìkọlù ọkàn ní ọjọ́ Kẹ́tá Oṣù Kiní ọdún 2015 lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ ọkàn. Ìròyìn wípé ó kú ní wákàtí diẹ̀ ṣáajú ayeye ìgbéyàwó ti ọmọbirin rẹ̀.[5][6]

Wo eléyì na[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Society lady, Mrs Adunni Bankole dies on daughter's wedding day". Linda Ikeji's Blog. January 3, 2015. Retrieved May 24, 2022. 
  2. Akinwale, Funsho (January 3, 2015). "Iyalode Adunni Bankole dies on daughter's wedding day -". The Eagle Online. Retrieved May 24, 2022. 
  3. Dede, Steve (January 5, 2015). "Lagos socialite, Adunni Bankole, dies on daughter’s wedding day". Pulse Nigeria. Retrieved May 24, 2022. 
  4. Citizen, The (January 4, 2015). "Adunni Bankole dies on daughter's wedding day". Nigerian Voice. Retrieved May 24, 2022. 
  5. "Bankole loses step-mother on daughter’s wedding day". Vanguard News. January 3, 2015. Retrieved May 24, 2022. 
  6. "Society Lady, Adunni Bankole, is Dead, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. January 19, 2015. Archived from the original on January 19, 2015. Retrieved May 24, 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)