Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Argungu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Argungu
Argungu
LGA and town
Nickname(s): 
Gungun Nabame
Argungu is located in Nigeria
Argungu
Argungu
Coordinates: 12°44′N 4°31′E / 12.733°N 4.517°E / 12.733; 4.517
Country Nigeria
StateKebbi State
Government
 • Sarkin KabbiAlhaji Samaila Muhammad Mera
Population
 (2007)
 • Total47,064
Time zoneUTC+1 (WAT)

Argungu jẹ́ ilú kan ní Ipinle Kebbi ní orílè-èdè Naijiria. Ní ọdún 2007, ìlú náà ní èrò tó n h lọ bíi 47,064.[1]

Ìsàn ọdọ̀ omi ti Sokoto, ìlú Argungu wà ní apá ilwọ̀-oòrùn, ní èbádò Sokoto.

Ọdún 1831 ni wọ́n kọ́ ilé Kanta Museum tí ó kọjú sí ọjà gbogboogbò ìlú náà. Wọ́n ń pe mùsíọ̀mù yìí lèyìn Muhammadu Kanta, tí ó ṣe ìdásílẹ̀ ìlú Kebbi ní ọdún 1515. [2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "The World Gazetteer". Archived from the original on October 1, 2007. Retrieved 2007-04-04.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Ayo Okulaja. "The charm of Argungu Museum". Next. Archived from the original on 2011-07-21. Retrieved 2010-10-08.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)