Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Arochukwu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Arochukwu)
Arochukwu

Aro-Okigbo
Country Nigeria
StateAbia State
Area
 • Total524 km2 (202 sq mi)
Population
 • Ethnicities
Igbo, Ibibio, and Akpa
 • Religions
Christianity, Traditional religions
3-digit postal code prefix
442
ISO 3166 codeNG.AB.AR

Agbegbe Ijoba Ibile Arochukwu tí àwọn miran ún pè ní Arochuku tàbí Aro Oke-Igbo jẹ́ ijoba ibile ni Ipinle Abia, orílè-èdè Nàìjíríà. Oun ni ilé fún àra ẹ̀yà igbo kan, tí wón ún jẹ́ Aro. Ẹ̀yà náà wá láti ìdílé márùn-ún, Abam, Aro, Ihechiowa, Ututu àti Ìṣù.

Àwọn èdè tí wọ́n ún sọ ní ìjọba ìbílè Arochukwu ni:[1]

  1. "Nigeria - Languages". Ethnologue, 22d edition. Feb 2019.