Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ilaje

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Ijaye)

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàjẹ jẹ́ ìjọba-ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Òǹdó tó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ gúnwà sí ìlú Igbokoda. Àwọn Ìlájẹ jẹ́ ẹ̀yà tí ó dá yàtọ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ sí etídò àwọn ẹ̀yà elédè Yorùbá tí wọ́n tàn yíká etí odò ìpínlẹ̀ Òndó, Ògún, Èkó, àti Delta.


Ìtàn ṣókí nípa Ilaje láti ẹnu ọmọ bíbí ìlú Ilaje.