Ile Oluji
Ile Oluji wà ní Nàìjíríà.[1].[2]
Ìpínlẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ilẹ̀ Olúji jẹ́ ìlú kan ní ìpínlẹ̀ Ondo orílẹ̀-èdè Nigeria.[3] Ìlú yìí jẹ́ olú- ìlú fún ìpínlẹ̀ Ile-Oluji/Okeigbo. Àwọn ìlú náà jẹ́ ọmọ Yorùbá tí babańlá wọ́n jẹ́ Oduduwa. Jegun of Ile-Oluji. Orúkọ ọba wọn. HRM Oba (Dr) Oluwole Olufaderin Adetimehin, FIIN, FCIB, Jimoko II, tí ó jẹ́ olórí ilé-ìfowópamọ́ Chartered Insurance Institute of Nigeria tẹ́lẹ̀ rí ni ọba wọn tuntun tí wọ́n dé ládé ní ọjọ́ kẹwàá, oṣù kẹfà, ọdún 2016 [4]
Ètò -ọrọ̀-ajé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ile-Oluji jẹ́ ìlú tí ó fàyè gba ètò- ọ̀gbìn. Ó jẹ́ ọkàn lára ìlú tí ó ń ṣe kòkó jù lọ ní orílè-èdè Nàìjíríà tí ó sì ń gbé e lọ sí àwọn orílè-èdè mìíràn .ẹ̀gẹ́, iṣu, àgbàdo, àti epo pupa jẹ àwọn ohun ọgbìn tí àwọn àgbè ìlú yìí tún máa ń tẹpele mọ́. Ilé-iṣẹ́ tó ṣe pàtàkì jù ní ìlú yìí ni Cocoa Products Ile-Oluji Limited.[5] Ó ní ọkàn nínú àwọn ilé-iṣẹ́ tó máa ń ṣe kòkó jù lọ ní ìwọ̀-oòrun Áfíríkà. Àwọn òhun tí ilé iṣẹ́ yìí ń ṣe ni Cocoa Powder, Cocoa Cake, Cocoa Butter àti Cocoa Liquor èyí tí wọ́n tà fún àwọn oníbàárà wọn. Lára àwọn oníbàárà wọ́n ni Promasidor Nigeria, Nestle, Fan Milk, Indcresa Productos Del Cacao ní Spain àti Theobroma B.V ní Netherlands. Oluji Pure Cocoa Powder jẹ́ ọ̀kan lára ohun tí ilé-iṣẹ́ yìí ṣe.
Ètò-ẹ̀kọ́.
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ilé-ìwé gíga ìjọba àpapọ̀ Pólì Federal Polytechnic, Ile-Oluji ni ilé-ìwé gíjà tó jẹ́ gbòógì ní ìlú yìí. Ilé-ìwé ìkọ́ṣẹ́ Asiwaju Bola Tinubu Skills Acquisition Centre, tí ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà kọ́ wà ní Ilẹ̀-Olúji.[6] Gboluji Grammar School, Ile-Oluji' jẹ́ ọkàn lára ọgọ́rùn-ún ilé-ìwé girama tó ti pẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[7] Àwọn ilé-ìwé girama mìíràn ní ìlú yìí ni Holy Saviour's High School, Orere Grammar School, Baptist High School, CAC Grammar School, St. Francis College, Gloryfield International College, New Era High School àti Akinyosoye Model College.
Àwọn ènìyàn tó lààmìlaaka ní Ile Oluji
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ènìyàn wọ̀nyí jẹ́ àwọn ènìyàn tó lààmìlaaka, tí wọ́n bi, tí ó gbé, tí ó sì ń gbé ní Ile-Oluji lọ́wọ́lọ́wọ́.
- Chief Henry Fajemirokun, CON. Businessman and industrialist. Former President, Nigerian Association of Chambers of Commerce, Industry, Mines and Agriculture NACCIMA.[8]
- Chief Oladele Fajemirokun - Businessman and philanthropist [9]
- Dr. Samuel Adesuyi - Nigeria's Chief Medical Adviser (1969 -1976).
- Chief Akinsola Akinfemiwa, OON - Former Managing Director, Skye Bank Plc.[10]
- Dr. Pius Olakunle Osunyikanmi - Director General, Directorate of Technical Aids Corps of Nigeria.[11]
- Professor Adebukola Foluke Osunyikanmi- Professor of Political Science[12]
- Ms Funke Opeke - Electrical Engineer and Founder, Main One Cable Company.[13]
- Senator Nicholas Tofowomo - Senator at the 9th National Assembly[14]
- Honourable Janet Febisola Adeyemi- Member, House of Representatives 1999 - 2003.[15]
- Late Professor Akin Akindoyeni , OFR - Pioneer Vice-Chancellor, Adekunle Ajasin University, Akungba.[16][17]
- Mr. Wale Akinterinwa - current Commissioner for Finance, Ondo State.[18]
- Pastor Wole Oladiyun - Founder, Christ Livingspring Apostolic Ministry CLAM[19]
- Professor Bola Akinterinwa - Former Director General, Nigerian Institute of International Affairs,[20]
- Professor Francis Afolabi Fajemirokun - Professor Emeritus of Surveying.[21][22]
- Professor Adeduro Adegeye - Professor of Agricultural Economics [23]
- Chief Bayo Akinbisehin, SAN - Legal Practitioner and Politician[24])
- Professor Robert Akinbowale Ogunsusi - Professor of Veterinary Medicine, Founding Provost of The Polytechnic-Ile-Oluji, Former Deputy Vice-Chancellor and Acting Vice-Chancellor, Federal University of Technology Akure[25]
- Mrs. Adejoke Orelope-Adefulire- Former Deputy Governor of Lagos State (2011 -2015)[26]
- Professor Ayo Ogunsheye - Professor of Adult Education, Ààrẹ̀, Lagos Chamber of Commerce and Industry láti ọdún 1983 sí 1987.[27]
- Professor Adetoun Ogunseye - Professor of Library Science; ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[28]
- Professor Anjuwon Akinwande - Professor of Mass communication[29]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ajakaye, Oluwaremilekun G.; Olusi, Titus Adeniyi; Oniya, M. O. (2016-06-01). "Environmental factors and the risk of urinary schistosomiasis in Ile Oluji/Oke Igbo local government area of Ondo State" (in en). Parasite Epidemiology and Control 1 (2): 98–104. doi:10.1016/j.parepi.2016.03.006. ISSN 2405-6731. https://www.sciencedirect.com/science/article/pii/S2405673115300428.
- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "History laws and customs of ILE-OLUJI" (in en-US). https://www.worldcat.org/title/history-laws-and-customs-of-ile-oluji/oclc/47757584.
- ↑ "The 31st Jegun Olu Ekun of Ile-Oluji" (in en-US). https://www.vanguardngr.com/2016/06/31st-jegun-olu-ekun-ile-oluji/.
- ↑ "Ile-Oluji Limited" (in en-US). Archived from the original on 2019-08-11. https://web.archive.org/web/20190811001726/http://ileolujicocoang.com/index.php.
- ↑ "Fed Govt opens skills acquisition centre in Ondo State" (in en-US). Archived from the original on 2021-01-27. https://web.archive.org/web/20210127204531/https://guardian.ng/news/fed-govt-opens-skills-acquisition-centre-in-ondo-state/.
- ↑ "Top 100 Oldest Secondary Schools In Nigeria And Year" (in en-US). Archived from the original on 2021-01-27. https://web.archive.org/web/20210127201940/https://nigeriatoplist.com/top-100-oldest-secondary-schools-in-nigeria-and-year/.
- ↑ Reporter (2021-12-07). "Remembering Nigeria’s Top Industrialist From Ile- Oluji , Henry Oloyede Fajemirokun". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-08.
- ↑ "Fajemirokun: I did not inherit my father’s businesses" (in en-US). Archived from the original on 2021-01-27. https://web.archive.org/web/20210127231135/https://guardian.ng/sunday-magazine/fajemirokun-i-did-not-inherit-my-fathers-businesses/.
- ↑ "Akinsola Akinfemiwa’s Destiny" (in en-US). https://www.thisdaylive.com/index.php/2019/09/08/akinsola-akinfemiwas-destiny/.
- ↑ "Mimiko’s divided house in Ondo". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-11-12. Retrieved 2022-04-08.
- ↑ "Adebukola Osunyinkanmi: Profile of a Seasoned Scholar". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-21. Retrieved 2022-04-08.
- ↑ Oludimu, Titilola (2017-05-05). "5 things you didn’t know about Funke Opeke, CEO of MainOne". Techpoint Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-08.
- ↑ "Sen Tofowomo proposes establishment of institute of culture, tourism in Ondo". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-08. Retrieved 2022-04-08.
- ↑ Ajumobi, Kemi (2020-10-02). "Women in Business: Janet Febisola Adeyemi". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-08.
- ↑ "AAUA Mourns Pioneer VC, Prof. Akindoyeni" (in en-US). Archived from the original on 2023-01-16. https://web.archive.org/web/20230116125117/https://thepolitico.com.ng/aaua-mourns-pioneer-vc-prof-akindoyeni/.
- ↑ "Professor Akin Akindoyeni OFR, mni" (in en-US). Archived from the original on 2021-01-19. https://web.archive.org/web/20210119220355/https://instituteofoilandgasresearch.org.ng/iogrhs-council/.
- ↑ "Profile of Mr. Adewale Olumuyiwa Akinterinwa" (in en-US). Archived from the original on 2021-01-20. https://web.archive.org/web/20210120161428/http://ondostate.gov.ng/Home/Team/b9c89f1b-fac4-42dc-b18f-75aba227e2b8.
- ↑ "Pastor Wole Oladiyun: ‘I Sold Spare Parts, Wood Before My Calling’" (in en-US). https://www.thisdaylive.com/index.php/2019/04/05/pastor-wole-oladiyun-i-sold-spare-parts-wood-before-my-calling/.
- ↑ "My father-in-law found out I was dating his daughter on TV –Prof. Akinterinwa" (in en-US). https://punchng.com/my-father-in-law-found-out-i-was-dating-his-daughter-on-tv-prof-akinterinwa/.
- ↑ "PROF. FRANCIS FAJEMIROKUN" (in en-US). Archived from the original on 2021-01-27. https://web.archive.org/web/20210127195117/http://magodoassociates.org/?ht_teacher=prof-francis-fajemirokun.
- ↑ "Francis Afolabi Fajemirokun" (in en-US). https://www.researchgate.net/profile/Francis_Fajemirokun.
- ↑ "DEPARTMENT OF AGRICULTURAL ECONOMICS" (in en-US). Archived from the original on 2021-01-28. https://web.archive.org/web/20210128055524/https://agric.ui.edu.ng/AJAdegeye.
- ↑ "AKINBISEHIN, Hon. Folorunso Adebayo" (in en-US). https://blerf.org/index.php/biography/hon-folorunso-adebayo-akinbisehin/.
- ↑ "(OPINION) Abiodun Adefulire: Home honour for distinguished retired Chief Magistrate". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-05. Retrieved 2022-04-08.
- ↑ admin (2021-11-22). "Adejoke Orelope-Adefulire: Senior Special Assistant to the President on Sustainable Development Goals (OSSAP-SDGs)". The Top10 Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-08.
- ↑ "OGUNSHEYE, Professor Ayo (Late)" (in en-US). https://blerf.org/index.php/biography/ogunsheye-professor-ayo/.
- ↑ "Celebrating ‘First Ladies’ of the professions" (in en-US). Archived from the original on 2023-05-28. https://web.archive.org/web/20230528111610/https://guardian.ng/guardian-woman/celebrating-first-ladies-of-the-professions/.
- ↑ "Akinwande Anjuwon" (in en-US). https://scholar.google.com/citations?user=qkXmycMAAAAJ&hl=en.