Jump to content

Ahmed Munir

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ahmed Munir je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati aṣofin lati àgbègbè Lere ni Ìpínlẹ̀ Kaduna ni Naijiria . [1]

Igbesi aye ibẹrẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi Ahmed Munir ni ojo kẹsàn-án osu kẹsàn-án odun 1981 ni àgbègbè Lere, ipinle Kaduna ni orile -ede Naijiria . [2]

Ahmed Munir jẹ́ olóṣèlú àti aṣòfin ní Nàìjíríà tó sì ń sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, tó ń ṣojú àwọn èèyàn ẹkùn ìpínlẹ̀ Lere. O jawe olubori ninu idibo odun 2023 labe ẹgbẹ òsèlú APC. [3]