Ajiya Abdulrahman
Ìrísí
Ajiya Abdulrahman je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o ṣiṣẹ gẹgẹbi ọmọ ẹgbẹ ti Ile-igbimọ aṣofin àgbà ti o nsójú Abaji / Gwagwalada / Kwali / Kuje (Abuja South) ti àgbègbè FCT Abuja ni apejọ orilẹ-ede kẹwàá. [1] [2] [3]