Akaanu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Akan Gye nyame adinkra.png
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
over 23 million
Regions with significant populations
 Ghánà 14 Million
 Côte d'Ivoire 8 Million
 Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan unknown
 Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan unknown
 Fránsì unknown
Èdè

Various Akan dialects

Ẹ̀sìn

Christianity, African traditional religion, Islam

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Akan

Akaanu, Akan

Àwon ènìyàn bíi mílíònù méjè ni ó ń so èdè yìí ní pàtàkì ní orílè-èdè Ghana. Wón tún ń so èdè yìí ní Cote d’lvoire àti Tógò. A máa ń lo Akan fún àwon èdè tí ó fara pera wònyí Ashante, fante àti iwì tí àwon tó ń so wón gbó ara won ní àgbóyé dáàyè kan sùgbón tí wón kà sí èdè òtòòlò nítorí àsà àti ònà ìgbà ko nnkan sílè won tí kò bára mu. Èdè ìsèjoba Àkotó Rómáànù ni wón lò láti ko ó sílè.