Jump to content

Akaanu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Akan)
Akan
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
over 23 million
Regions with significant populations
 Ghánà 14 Million
 Côte d'Ivoire 8 Million
 Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan unknown
 Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan unknown
 Fránsì unknown
Èdè

Various Akan dialects

Ẹ̀sìn

Christianity, African traditional religion, Islam

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Akan

Akaanu, Akan

Àwọn ènìyàn bíi mílíọ̀nù méjè ni ó ń sọ èdè yìí ní pàtàkì ní orílẹ̀-èdè Ghana. Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní Cote d’lvoire àti Tógò. A máa ń lo Akan fún àwọn èdè tí ó fara pera wọ̀nyí Ashante, fante àti iwì tí àwọn tó ń sọ wọ́n gbọ́ ara wọn ní àgbóyé dáàyè kan ṣùgbọ́n tí wọ́n kà sí èdè òtọ̀ọ̀lọ̀ nítorí àṣà àti ọ̀nà ìgbà kọ nǹkan sílẹ̀ wọn tí kò bára mu. Èdè ìṣèjọba Àkọtọ́ Rómáànù ni wọ́n lò láti kọ ọ́ sílè.