Aláàfin Ọbalokùn
Ìrísí
Obalokun fìgbà kan jẹ́ as an Aláàfin ìlú Ọ̀yọ́. Àsìkò rẹ̀ jẹ́ èyí tó tó kún fún àlàáfíà àti ìgbé ayé ìrọ̀rùn.
Ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọmọbìnrin Alake tó jẹ́ ọmọ Ẹ̀gbá ni ìyá Obalokun Agana Erin.
Gẹ́gẹ́ bí ìtàn Ọ̀yọ́ ṣe fi lélẹ̀, ó wà ní ìbánisọ̀rọ̀ pẹ̀lú ọba Faranse tàbí ti Portugal.[1]
Aláàfin Àjàgbó ló jẹ́ oyè yìí, lẹ́yìn tó wàjà.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Johnson, Samuel (2011). History of the yorubas. Research Associates School. ISBN 0948390891. OCLC 841599526.