Alfred Adler

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Alfred Adler
Ọjọ́ìbí (1870-02-07)Oṣù Kejì 7, 1870
Rudolfsheim, Austria
Aláìsí May 28, 1937(1937-05-28) (ọmọ ọdún 67)
Aberdeen, Scotland
Ibùgbé Austria
Orílẹ̀-èdè Austrian
Iṣẹ́ Psychiatrist
Known for Individual Psychology
Spouse(s) Raissa Epstein

Alfred Adler je onisegun omo ile Austria. Wón bí Adler ní 1870. Ó kú ní 1937. Omo ilè Austria ni. Olù-wò-wèrè tàbí olù-tójú-alárùn-opolo (psychiatrist) ni. Òun ni ó dá ilé-èkó tí ó n jé ‘School of Individual psychology’ sílè. Freud ni ó kókó n tè lé sùgbón ó yapa kúrò ní òdò rè 1911. Ó tako ìtenpele mó òrò ìbára-eni lòpò (sex). Lójú rè, wàhálà tí ènìyàn ni láti sa agbara láti yo ara eni kúrò ní ipò eni àá fojú ténbélú (inferiority Complex).


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]