Aliyu Mai-Bornu
Ìrísí
Aliyu Mai-Bornu | |
---|---|
Governor of the Central Bank of Nigeria | |
In office Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1963 – Ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹfà ọdún 1967 | |
Asíwájú | Roy Pentelow Fenton |
Arọ́pò | Clement Nyong Isong |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ọdún 1919 |
Aláìsí | Ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 1970 |
Mallam Aliyu Mai-Bornu tí wọ́n bí ní ọdún 1919, tí ó sì ṣaláìsí lọ́jọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 1970 (1919 - 23 February 1970) jẹ́ òkúná-gbòǹgbò onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ tó jẹ́ Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Alhaji Aliyu Mai-Bornu". Central Bank of Nigeria. Retrieved 2010-02-28.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |