Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà
Fáìlì:CBNLogo.png
Headquarters Abuja, FCT, Nigeria
Established 1958
Central Bank of Nigeria
Currency Nigerian naira
ISO 4217 Code NGN 566
Website cbn.gov.ng
CBN headquarters
Central Bank of Nigeria

Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà jẹ́ Ilé-ìfowópamọ́-àgbà tí ó ń ṣe kòkárí àti ìmójútó àwọn ilé Ìfowópamọ́ káràkátà lábẹ́ òfin Ìfowópamọ́ tí Ìjọba Àpapọ̀ gbé kalẹ̀ lọ́dún 1958, tí ó sìn bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kìíní oṣù keje ọdún 1959.[1] Ó. Jẹ́ Ilé-ìfowópamọ́ fún àwọn Ilé-ìfowópamọ́[2]. Gómìnà ní orúkọ oyè tí Adarí yànyàn tí ó máa ń darí Ilé Ìfowópamọ́-àgbà máa ń jẹ́. Godwin EmefieleGómìnà Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí ó wà lórí àléfà lọ́wọ́́lọ́wọ́.[2] Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan ló yàn án lọ́dún 2014, lẹ́yìn èyí, Ààrẹ Muhammadu Buhari tún ṣe àtúnyàn rẹ̀ lọ́dún 2018 fún sáà Elékejì. [3].

Àtòjọ Àwọn Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ àgbà ti Nàìjíríà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn wọ̀nyí ni Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ àgbà ti Nàìjíríà tí ó ti jẹ láti ọdún 1960 títí di àkókò yìí:[4]

Governor Previous position Term start Term end
Roy Pentelow Fenton 24 July 1958 24 July 1963
Aliyu Mai-Bornu Deputy Governor, CBN 25 July 1963 22 June 1967
Clement Nyong Isong Advisor International Monetary Fund 15 August 1967 22 September 1975
Adamu Ciroma 24 September 1975 28 June 1977
Ola Vincent Deputy Governor, CBN 28 June 1977 28 June 1982
Abdulkadir Ahmed Deputy Governor, CBN 28 June 1982 30 September 1993
Paul Agbai Ogwuma CEO, Union Bank of Nigeria 1 October 1993 29 May 1999
Joseph Oladele Sanusi CEO First Bank of Nigeria 29 May 1999 29 May 2004
Charles Chukwuma Soludo Chief Executive, National Planning Commission 29 May 2004 29 May 2009
Sanusi Lamido Aminu Sanusi CEO, First Bank of Nigeria 3 June 2009 20 February 2014[5]
Sarah Alade Deputy Governor, Central Bank of Nigeria 20 February 2014 3 June 2014
Godwin Emefiele Chief Executive Officer, Zenith Bank 3 June 2014 to date[5][6]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "History of CBN". cenbank.org. Central Bank of Nigeria. Retrieved 25 September 2018. 
  2. 2.0 2.1 ":: Central Bank of Nigeria : Monetary Policy Functions". Central Bank of Nigeria | Home. 2006-02-20. Retrieved 2020-01-14.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Central Bank of Nigeria | Home 2006" defined multiple times with different content
  3. "Godwin Emefiele, Central Bank of Nigeria: Profile and Biography". Bloomberg.com. 2019-02-07. Retrieved 2020-01-14. 
  4. "Past And Present Governors". Central Bank of Nigeria. Retrieved 2010-02-28. 
  5. 5.0 5.1 "Nigeria central bank head Lamido Sanusi ousted". bbc.com. BBC. Retrieved 25 September 2018. 
  6. "BREAKING: Senate confirms Emefiele’s re-appointment a day after screening". Oak TV Newstrack. 16 May 2019. https://oak.tv/newstrack/breaking-senate-confirms-emefiele/. Retrieved 17 May 2019.