Allah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Allah (Lárúbáwá: اللهAllāh, IPA: [ʔalˤːɑːh]  ( listen)) ni oro fun Olorun ni ede Arabiki.[1] Botilejepe a mo nibo miran bi oro awon musulumu fun Olorun, oro yi gbogbo na ni awon Arabu yioku onigbagbo Abrahamu unlo fun "Olorun", awon bi Mizrahi Jews, Baha'is ati Eastern Orthodox Christians.[1][2][3] Oro yi na tun ni awon keferi ara Meka na tu lo fun olorun-eleda, o seese ko je orisa igba na ni Arabia akosiwaju-Imale.[4][5]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Allah." Encyclopædia Britannica. 2007. Encyclopædia Britannica
  2. Encyclopedia of the Modern Middle East and North Africa, Allah
  3. Columbia Encyclopedia, Allah
  4. L. Gardet, "Allah", Encyclopedia of Islam
  5. Smith, Peter (2000). "prayer". A concise encyclopedia of the Bahá'í Faith. Oxford: Oneworld Publications. pp. 274–275. ISBN 1-85168-184-1.