Allwell Adémọ́lá
Ìrísí
Allwell Adémọ́lá tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Ọjọ́ Kẹ̀sán-án oṣù kẹjọ ọdún 1983 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí, oǹkọ̀tàn, akọrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ-ọmọbìnrin adájọ́-àgbà jùlọ àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà, Adájọ́-Àgbà, Olóògbé Adétòkunbọ̀ Adémọ́lá . [1]
Ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìgbà èwe rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí ní ifáfitì ìjọba àpapọ̀ tó gúnwà sí Ilé-Ifẹ̀, OAU. Allwell bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò láti èwe ṣùgbọ́n ní ọdún 2008 ni ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimá àgbéléwò. Láti ìgbà náà, ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò, lára àwọn sinimá-àgbéléwò tó gbé ìràwọ̀ rẹ̀ síta ni; Láródó Ọjọ́, Etí kẹta, Ọmọ Ẹ̀mí, You. Or I, Ayé Kejì.[2]
Àtòjọ díè nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- [[Ayé Kejì]
- Ìdájọ́
- Tiwa's Baggage
- (Àmódí)
- Òdèré Olóńjẹ
- Ọmọ Ẹ̀mí
- Side Chic Squad
- False Flag
- Kílà
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Allwell Ademola Biography: Age, Movies". 360dopes. 2018-07-29. Retrieved 2020-02-09.
- ↑ [/allwell-ademola-biography-profile-fabwoman/ "Allwell Ademola Biography - Profile"] Check
|url=
value (help). FabWoman | News, Style, Living Content For The Nigerian Woman. 2019-08-09. Retrieved 2020-02-09.