Aluminium ní Áfríkà
Ìrísí
Àwọn Aluminium ní Áfríkà búyọ láti ara àpáta bauxite, wọ́n sì ń rí wọn ní àwọn orílẹ̀-èdè bi Guinea, Mozambique àti Ghana. Guinea ni órílẹ̀ èdè tí ó ń ṣe aluminium jáde jù ní Áfríkà, òun sì tún lọ ṣàgbéjáde òkúta bauxite jùlọ.
Ọ̀pọ̀lopọ̀ orílẹ̀ èdè ni ó wà nínú títà àti rírà aluminium ní Áfríkà. Àwọn bi:
- Ghana Bauxite, wọ́n ní ìbásepọ̀ pẹ̀lú Alcan
- Volta Aluminum Company (Valco)
- Rio Tinto Alcan
- Compagnie des Bauxites de Guinée (CBG) - ní agbègbè Boké.
- Alumina Company of Guinea, ACG - wọ́n ṣiṣẹ́ ní Friguia bauxite-alumina complex ní Fria[1]
- Societé des Bauxites de Kindia SBK.
- Global Alumina Products Corporation.
- Kinia - refinery [1]
- Sangaredi
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 http://railwaysafrica.com/index.php?option=com_content&task=view&id=3381&Itemid=35
- ↑ "Mozambique: Mozal Suffers From South African Energy Crisis". Agencia de Informacao de Mocambique (Maputo). 2008-06-10. http://allafrica.com/stories/200806101031.html.