Jump to content

Alvan Ikoku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Alvan Ikoku je ara Naijiria(ti a bi ni ọjọ kínní oṣù kẹjọ ọdún 1900- ojo kejidinlogun oṣù kọkànlá ọdún 1972) O jẹ olukọni,ajijagbara ati olóṣèlú

Ìgbé ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ti a bi ni ọjọ kínní oṣù kẹjọ, 1900, ni Amanagwu Arochukwu, ti a n pe ni Ìpínlẹ̀ Ábíá, láti ọdún 1911 sí ọdún 1914,ọ ka ìwé akẹkọ béèrè ni Arochukwu Government Primary School lati ọdún 1915 sí ọdún 1920,[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Alvan Azinna Ikoku, a revolutionary educationist". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-09-08. Retrieved 2022-03-06.