Jump to content

Amadou & Mariam

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Amadou & Mariam
Mariam Doumbia and Amadou Bagayoko
Mariam Doumbia and Amadou Bagayoko
Background information
Ìbẹ̀rẹ̀ Bamako, Mali
Irú orinMalian music, Worldbeat
Years active1974 - Present
LabelsBecause Music, Nonesuch Records
Websitehttp://www.amadou-mariam.com/
MembersAmadou Bagayoko
Mariam Doumbia

Amadou & Mariam je awon eniyan meji olorin lati Mali, awon ni Amadou Bagayoko (gita ati ohun) (ojoibi Bamako 24 October 1954) ati Mariam Doumbia (ohun) (ojoibi Bamako 15 April 1958). Awon mejeji pade ni Ile-Eko fun awon Odo Afoju ti Mali nibi ti won ti ri pe awon mejeji feran orin kiko.