Odò Amasónì
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Amazon River)
Amazon River | |
River | |
Mouth of the Amazon River
| |
Àwọn orílẹ̀-èdè | Perú, Kòlómbìà, Brasil, Bòlífíà, Fenesuela, Ẹ̀kùàdọ̀r, Gùyánà |
---|---|
State | 34 |
Region | South America |
Tributaries | |
- left | Marañón, Japurá, Rio Negro |
- right | Ucayali, Purus, Madeira, Tapajós, Xingu, Tocantins |
Ìlú | Iquitos (Peru); Manaus (Brazil) and Belém do Pará (Brazil). |
Source | Apacheta cliff |
- location | Nevado Mismi, Arequipa, Peru |
- elevation | 5,170 m (16,962 ft) |
- coordinates | 15°31′05″S 71°45′55″W / 15.51806°S 71.76528°W |
Mouth | |
- location | Atlantic Ocean, Brazil |
- elevation | 0 m (0 ft) |
Length | 6,400 km (4,000 mi) approx. |
Basin | 7,050,000 km² (2,720,000 sq mi) approx. |
Discharge | mouth |
- average | 219,000 m3/s (7,734,000 cu ft/s) |
Odo Amasonini odo to tobijulo lagbaye. Awon oniwadii kan ni ile Brazil ti so pe odo Amazon ni o gun ju ni agbaye. Teletele, odo Amazon ni a mo pe o ni omi ninu ju lo ni gbogbo agbaye ti o si je pe odo Nile ni o gun ju sugbon, awon oniwadii yii so pe Mismi ni ile Peru ni Amazon ti bere ati pe o gun ni iwon 6,800 km (4,250 miles) ni gba ti Nile si gun ni iwon 6,695 km.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |