Jump to content

Odò Amasónì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Amazon River
River
Mouth of the Amazon River
Àwọn orílẹ̀-èdè  Perú,  Kòlómbìà,  Brasil,  Bòlífíà,  Fenesuela,  Ẹ̀kùàdọ̀r,  Gùyánà
State 34
Region South America
Tributaries
 - left Marañón, Japurá, Rio Negro
 - right Ucayali, Purus, Madeira, Tapajós, Xingu, Tocantins
Ìlú Iquitos (Peru); Manaus (Brazil) and Belém do Pará (Brazil).
Source Apacheta cliff
 - location Nevado Mismi, Arequipa, Peru
 - elevation 5,170 m (16,962 ft)
 - coordinates 15°31′05″S 71°45′55″W / 15.51806°S 71.76528°W / -15.51806; -71.76528
Mouth
 - location Atlantic Ocean, Brazil
 - elevation m (0 ft)
Length 6,400 km (4,000 mi) approx.
Basin 7,050,000 km² (2,720,000 sq mi) approx.
Discharge mouth
 - average 219,000 m3/s (7,734,000 cu ft/s)
Map showing the Amazon drainage basin with the Amazon River highlighted

Odo Amasonini odo to tobijulo lagbaye. Awon oniwadii kan ni ile Brazil ti so pe odo Amazon ni o gun ju ni agbaye. Teletele, odo Amazon ni a mo pe o ni omi ninu ju lo ni gbogbo agbaye ti o si je pe odo Nile ni o gun ju sugbon, awon oniwadii yii so pe Mismi ni ile Peru ni Amazon ti bere ati pe o gun ni iwon 6,800 km (4,250 miles) ni gba ti Nile si gun ni iwon 6,695 km.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]